Ọ̀Rọ̀ Àgbà[yorùbá] Poem by Hell 'Farya

Ọ̀Rọ̀ Àgbà[yorùbá]

Emi wi fun yin -

À'ferìgì j'obi tí f'eyin jẹ ẹran rì,
Omo pelu baba,
Ere asapajude ni toun sa,
Eyi pelu o bikita,
O ni egungun a'fikaja lorun ni,
Bi jije ba di eewo,
Ni se ni oun yoo pon la.

Ere ni oun ko le sa,
Beeni ayo ni baba n ta lori irin,
Oro iyanju kan ko si,
Tete oun oti ni emi re,
O ni aye ajepe, ajepe.

Emi duro lori afara,
Oun ti mo ri koro ko se e fenu so,
Iwaju wa da'feyin lo,
Eye igun fe'gbe lo so bi asa,
Owo agba pelu maalu meeje,
Sebi gbangba l'asa n fo,
Eyi se wa fi owu di'ju.

Ni igba ìwáṣẹ̀,
Arakunrin omodunmerinlelogbon,
O fa'riga f'egberin,
Okuta ikose ko ni ye mo si,
Otun oun osi laye n yi lo fi kewo.

POET'S NOTES ABOUT THE POEM
Check out the English version
COMMENTS OF THE POEM
READ THIS POEM IN OTHER LANGUAGES
Close
Error Success